@fornyboy1 on Quibbles
@fornyboy1
Joined May 2026
- 139posts
- 638comments
- 0connections
Moderates
VOICE NOTE ÌKẸYÌN
Ní aago 2:13 òru, fóònù mi mì. Voice note kan wà lórí WhatsApp — látọ̀dọ̀ Màmá.Ọkàn mi fẹ́ já. Màmá mi ti kú fún oṣù mẹ́ta.Mo tẹ̀ ẹ́. "David… tí o bá ń gbọ́ ohun yìí, jọ̀wọ́ fetí sí mi." Ohùn Màmá gan-an ni, ohùn tí mo mọ̀ láti kékeré. Lẹ́yìn náà, ó ...