KOKO QUIBBLES
Eku ikale oo, esi ku dede iwo yi emi ni omo yin ati ore yin Johanna.Mowanibi loni lati wa soro nipa koko appu yi ti e wa Lori re nisiyi emabamikalo!!
Lakoko momaa soro nipa bi appu yii seje: appu yii ti a mo si"quibbles" oje appu idaraeniya eyi ti awon oyinbo npe ni "entertainment" orisirisi ni eto idanilaraya na pin si. See bi osele dasi awon ibere Pataki ti o jeyo nhi, tabi bi o sele kopa ninu nkan ti awon ore re se ni abi se bi o ti le mo nkan ti oun sele lowo lagbegbe re ni ani appu yii rewa o si dun pupo.
Ni abala keeji uno maa so nipa bi appu yii se n koni loye toyekoro lojojumo lati ipase awon omo egbe naa ti won fi oye yewa nipa nkan ti oun sele layika wa ki ale mo ijinle otito ninu iro ti ati gbo lati ita.
Nkan iketa ti un nyo so ni pe ayee wa fun onilaluku lati gba ebun si ibere ti o ba dahun si ti o si gba daradara ni oo.
Gbogbo eyin ti nka oro yii nisisiyi eyin sesede ni oo tabi eyin atilewa oro mi fun yin nipe emase sole etepamoseyin ooo ki ele ba egbun yin ooooo. ESE GAN NI O
5 comments
Log in to join the conversationAdupe ooo
Ise ya
👏👏👏
Eku jo koo
ESE oo